Nigba ti Marthinus, to jẹ agbẹ n ṣalaye ipo to wa pẹlu odi onirin to yi ka pẹlu ọpọ kamẹra to n wo o, o ni ṣe lo da bii pe inu ẹwọn loun wa. O ni "O daa bii pe inu ẹwọn ni mo wa; wọn le wa pa wa ti ...